Donate to IDDU
Pay Subscription
Ibadan Anthem
Ibadan Ilu Ori oke
Ilu Ibukun Oluwa
K"Oluwase o nibukun
Fun Onile at"Alejo
Egbe; Eho e yo ke si gberin
Ogo f"Olorun wa lo"orun
Ibukun ti Obangiji
Wa pelu re wo Ibadan
Mo wo lati ori oke
Bi ewa re ti dara to
B"odore kotile dara
Sibe o la ibadan ja
Egbe; Eho e yo ke si gberin
Ibadan Ilu ori oke
K"Oluwa se o nibukun
Ki gbogbo joye inu re
Je elemi gigun fun wa
Egbe;Eho e yo ke si gberin
Ibadan Ilu to ngbajeji
Tiko si gbagbe omore
kife ara ko wa sibe
Fun Onile at"Alejo
Egbe;Eho e yo ke si gberin
Ibadan ilu Jagunjagun
Awonto so o dilu nla
Awa omo re ko ni je
K"ola ti ogo won run
Egbe; Eho e yo ke si gberin